Léfítíkù 25:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ ta ilẹ̀ náà títí láé,+ torí tèmi ni ilẹ̀ náà.+ Ojú àjèjì àti àlejò ni mo fi ń wò yín.+ 24 Kí ẹ jẹ́ kí ẹ̀tọ́ láti ra ilẹ̀ pa dà wà ní gbogbo ilẹ̀ tó jẹ́ tiyín.
23 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ ta ilẹ̀ náà títí láé,+ torí tèmi ni ilẹ̀ náà.+ Ojú àjèjì àti àlejò ni mo fi ń wò yín.+ 24 Kí ẹ jẹ́ kí ẹ̀tọ́ láti ra ilẹ̀ pa dà wà ní gbogbo ilẹ̀ tó jẹ́ tiyín.