Ìsíkíẹ́lì 39:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Mi ò ní fi ojú mi pa mọ́ fún wọn mọ́,+ torí màá tú ẹ̀mí mi sórí ilé Ísírẹ́lì,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”
29 Mi ò ní fi ojú mi pa mọ́ fún wọn mọ́,+ torí màá tú ẹ̀mí mi sórí ilé Ísírẹ́lì,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”