Àìsáyà 32:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí wọ́n ti pa ilé gogoro tó láàbò tì;Wọ́n ti pa ìlú aláriwo tì.+ Ófélì+ àti ilé ìṣọ́ ti di ahoro títí láé,Ààyò àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó,Ibi ìjẹko àwọn agbo ẹran,+15 Títí dìgbà tí a bá tú ẹ̀mí jáde sórí wa látòkè,+Tí aginjù di ọgbà eléso,Tí a sì ka ọgbà eléso sí igbó.+ Jóẹ́lì 2:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Lẹ́yìn ìyẹn, èmi yóò tú ẹ̀mí mi + sára onírúurú èèyàn,Àwọn ọmọ yín lọ́kùnrin àti lóbìnrin yóò sì máa sọ tẹ́lẹ̀,Àwọn àgbà ọkùnrin yín yóò máa lá àlá. Àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín yóò sì máa rí ìran.+
14 Torí wọ́n ti pa ilé gogoro tó láàbò tì;Wọ́n ti pa ìlú aláriwo tì.+ Ófélì+ àti ilé ìṣọ́ ti di ahoro títí láé,Ààyò àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó,Ibi ìjẹko àwọn agbo ẹran,+15 Títí dìgbà tí a bá tú ẹ̀mí jáde sórí wa látòkè,+Tí aginjù di ọgbà eléso,Tí a sì ka ọgbà eléso sí igbó.+
28 Lẹ́yìn ìyẹn, èmi yóò tú ẹ̀mí mi + sára onírúurú èèyàn,Àwọn ọmọ yín lọ́kùnrin àti lóbìnrin yóò sì máa sọ tẹ́lẹ̀,Àwọn àgbà ọkùnrin yín yóò máa lá àlá. Àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín yóò sì máa rí ìran.+