Ìsíkíẹ́lì 36:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Èmi yóò fún yín ní ọkàn tuntun,+ màá sì fi ẹ̀mí tuntun sínú yín.+ Màá mú ọkàn òkúta+ kúrò lára yín, màá sì fún yín ní ọkàn ẹran.*
26 Èmi yóò fún yín ní ọkàn tuntun,+ màá sì fi ẹ̀mí tuntun sínú yín.+ Màá mú ọkàn òkúta+ kúrò lára yín, màá sì fún yín ní ọkàn ẹran.*