-
Ẹ́sírà 1:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ta ni nínú yín tó jẹ́ èèyàn rẹ̀? Kí Ọlọ́run rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀, kí ó lọ sí Jerúsálẹ́mù tó wà ní Júdà, kí ó sì tún ilé Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì kọ́, òun ni Ọlọ́run tòótọ́, tí ilé rẹ̀ wà ní Jerúsálẹ́mù.*
-
-
Émọ́sì 9:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 ‘Màá gbìn wọ́n sórí ilẹ̀ wọn,
A kò sì ní fà wọ́n tu mọ́
Kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún wọn,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ wí.”
-