-
Jeremáyà 32:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Àwọn èèyàn á tún ra ilẹ̀ ní ilẹ̀ yìí,+ bí ẹ tilẹ̀ ń sọ pé: “Ahoro ni, tí kò sí èèyàn àti ẹranko lórí rẹ̀, a sì ti fi í lé ọwọ́ àwọn ará Kálídíà.”’
-