ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 7:16, 17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ilé rẹ àti ìjọba rẹ máa fẹsẹ̀ múlẹ̀ títí láé níwájú rẹ; ìtẹ́ rẹ á sì fìdí múlẹ̀ títí láé.”’”+

      17 Nátánì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí àti gbogbo ìran tó rí+ fún Dáfídì.

  • 2 Sámúẹ́lì 23:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ǹjẹ́ kì í ṣe bí ilé mi ṣe rí nìyẹn lójú Ọlọ́run?

      Torí ó ti bá mi dá májẹ̀mú ayérayé,+

      Tó wà létòlétò, tó sì wà lábẹ́ ààbò.

      Nítorí ó jẹ́ ìgbàlà mi látòkèdélẹ̀ àti gbogbo ìdùnnú mi,

      Ǹjẹ́ kì í ṣe ìdí tó fi ń mú kó gbilẹ̀+ nìyẹn?

  • Sáàmù 89:34, 35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Mi ò ní da májẹ̀mú mi,+

      Mi ò sì ní yí ohun tí ẹnu mi ti sọ pa dà.+

      35 Mo ti búra nínú ìjẹ́mímọ́ mi, lẹ́ẹ̀kan láìtún ṣe é mọ́;

      Mi ò ní parọ́ fún Dáfídì.+

  • Sáàmù 132:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Jèhófà ti búra fún Dáfídì,

      Ó dájú pé kò ní ṣàìmú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ pé:

      “Ọ̀kan lára ọmọ* rẹ

      Ni màá gbé gorí ìtẹ́ rẹ.+

  • Àìsáyà 55:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ẹ dẹ etí yín sílẹ̀, kí ẹ sì wá sọ́dọ̀ mi.+

      Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ* ó sì máa wà láàyè nìṣó,

      Ó sì dájú pé màá bá yín dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé+

      Bí mo ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó jẹ́ òótọ́,* hàn sí Dáfídì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́