Àìsáyà 14:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí Jèhófà máa ṣàánú Jékọ́bù,+ ó sì máa tún Ísírẹ́lì yàn.+ Ó máa mú kí wọ́n gbé* ní ilẹ̀ wọn,+ àwọn àjèjì máa dara pọ̀ mọ́ wọn, wọ́n sì máa sọ ara wọn di ará ilé Jékọ́bù.+ Jeremáyà 31:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Ǹjẹ́ Éfúrémù kì í ṣe ọmọ mi àtàtà, ọmọ tí mo nífẹ̀ẹ́?+ Torí bí mo ṣe ń sọ̀rọ̀ sí i tó, síbẹ̀ mo ṣì ń rántí rẹ̀. Ìdí nìyẹn tí ọkàn* mi fi gbé sókè nítorí rẹ̀.+ Ó sì dájú pé màá ṣàánú rẹ̀,” ni Jèhófà wí.+
14 Torí Jèhófà máa ṣàánú Jékọ́bù,+ ó sì máa tún Ísírẹ́lì yàn.+ Ó máa mú kí wọ́n gbé* ní ilẹ̀ wọn,+ àwọn àjèjì máa dara pọ̀ mọ́ wọn, wọ́n sì máa sọ ara wọn di ará ilé Jékọ́bù.+
20 “Ǹjẹ́ Éfúrémù kì í ṣe ọmọ mi àtàtà, ọmọ tí mo nífẹ̀ẹ́?+ Torí bí mo ṣe ń sọ̀rọ̀ sí i tó, síbẹ̀ mo ṣì ń rántí rẹ̀. Ìdí nìyẹn tí ọkàn* mi fi gbé sókè nítorí rẹ̀.+ Ó sì dájú pé màá ṣàánú rẹ̀,” ni Jèhófà wí.+