Jeremáyà 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ kéde rẹ̀ ní Júdà, ẹ sì polongo rẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù. Ẹ kígbe, kí ẹ sì fun ìwo jákèjádò ilẹ̀ náà.+ Ẹ gbóhùn sókè, kí ẹ sì sọ pé: “Ẹ kóra jọ,Ẹ sì jẹ́ kí a sá wọ àwọn ìlú olódi.+
5 Ẹ kéde rẹ̀ ní Júdà, ẹ sì polongo rẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù. Ẹ kígbe, kí ẹ sì fun ìwo jákèjádò ilẹ̀ náà.+ Ẹ gbóhùn sókè, kí ẹ sì sọ pé: “Ẹ kóra jọ,Ẹ sì jẹ́ kí a sá wọ àwọn ìlú olódi.+