Jeremáyà 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ wá ibi ààbò kúrò ní Jerúsálẹ́mù, ẹ̀yin ọmọ Bẹ́ńjámínì. Ẹ fun ìwo+ ní Tékóà;+Ẹ sì gbé àmì iná sókè lórí Bẹti-hákérémù! Torí pé àjálù ń rọ̀ dẹ̀dẹ̀ láti àríwá, àjálù ńlá.+
6 Ẹ wá ibi ààbò kúrò ní Jerúsálẹ́mù, ẹ̀yin ọmọ Bẹ́ńjámínì. Ẹ fun ìwo+ ní Tékóà;+Ẹ sì gbé àmì iná sókè lórí Bẹti-hákérémù! Torí pé àjálù ń rọ̀ dẹ̀dẹ̀ láti àríwá, àjálù ńlá.+