Ẹ́kísódù 21:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Tí o bá ra Hébérù kan ní ẹrú,+ kí ó sìn ọ́ fún ọdún mẹ́fà, àmọ́ ní ọdún keje, kí o dá a sílẹ̀ láìgba ohunkóhun.+ Léfítíkù 25:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí ẹ ya ọdún àádọ́ta (50) sí mímọ́, kí ẹ sì kéde òmìnira fún gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà.+ Yóò di Júbílì fún yín, kálukú yín á pa dà sídìí ohun ìní rẹ̀, kálukú yín á sì pa dà sọ́dọ̀ ìdílé rẹ̀.+
2 “Tí o bá ra Hébérù kan ní ẹrú,+ kí ó sìn ọ́ fún ọdún mẹ́fà, àmọ́ ní ọdún keje, kí o dá a sílẹ̀ láìgba ohunkóhun.+
10 Kí ẹ ya ọdún àádọ́ta (50) sí mímọ́, kí ẹ sì kéde òmìnira fún gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà.+ Yóò di Júbílì fún yín, kálukú yín á pa dà sídìí ohun ìní rẹ̀, kálukú yín á sì pa dà sọ́dọ̀ ìdílé rẹ̀.+