Jeremáyà 32:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Wọ́n ń kẹ̀yìn sí mi dípò kí wọ́n máa yíjú sí mi; + bí mo tiẹ̀ ń kọ́ wọn léraléra,* kò sí ìkankan nínú wọn tó fetí sílẹ̀, tó sì gba ìbáwí.+
33 Wọ́n ń kẹ̀yìn sí mi dípò kí wọ́n máa yíjú sí mi; + bí mo tiẹ̀ ń kọ́ wọn léraléra,* kò sí ìkankan nínú wọn tó fetí sílẹ̀, tó sì gba ìbáwí.+