2 Kíróníkà 29:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí àwọn bàbá wa ti hùwà àìṣòótọ́, wọ́n sì ti ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà Ọlọ́run wa.+ Wọ́n fi í sílẹ̀, wọ́n yí ojú wọn kúrò níbi àgọ́ ìjọsìn Jèhófà, wọ́n sì kẹ̀yìn sí i.+ Jeremáyà 2:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Wọ́n sọ fún igi pé, ‘Ìwọ ni bàbá mi’+Àti fún òkúta pé, ‘Ìwọ ni o bí mi.’ Wọ́n kẹ̀yìn sí mi dípò kí wọ́n kọjú sọ́dọ̀ mi.+ Ní àkókò àjálù wọn, wọ́n á sọ pé,‘Dìde, kí o sì gbà wá!’+
6 Nítorí àwọn bàbá wa ti hùwà àìṣòótọ́, wọ́n sì ti ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà Ọlọ́run wa.+ Wọ́n fi í sílẹ̀, wọ́n yí ojú wọn kúrò níbi àgọ́ ìjọsìn Jèhófà, wọ́n sì kẹ̀yìn sí i.+
27 Wọ́n sọ fún igi pé, ‘Ìwọ ni bàbá mi’+Àti fún òkúta pé, ‘Ìwọ ni o bí mi.’ Wọ́n kẹ̀yìn sí mi dípò kí wọ́n kọjú sọ́dọ̀ mi.+ Ní àkókò àjálù wọn, wọ́n á sọ pé,‘Dìde, kí o sì gbà wá!’+