-
Jeremáyà 40:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ìgbà náà ni olórí ẹ̀ṣọ́ mú Jeremáyà, ó sì sọ fún un pé: “Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló sọ pé àjálù yìí máa bá ibí yìí,
-
-
Jeremáyà 40:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ní báyìí, màá tú ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ tó wà ní ọwọ́ rẹ kúrò lónìí. Tí o bá fẹ́ bá mi lọ sí Bábílónì, jẹ́ ká lọ, màá sì tọ́jú rẹ. Ṣùgbọ́n bí o kò bá fẹ́ tẹ̀ lé mi lọ sí Bábílónì, dúró ẹ. Wò ó! Gbogbo ilẹ̀ náà pátá wà níwájú rẹ. Ibikíbi tí o bá fẹ́ ni kí o lọ.”+
-