Jeremáyà 39:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nebukadinésárì* ọba Bábílónì sì pàṣẹ fún Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ nípa Jeremáyà, pé: 12 “Mú un, kí o sì tọ́jú rẹ̀; má hùwà ìkà sí i, kí o sì fún un ní ohunkóhun tó bá béèrè lọ́wọ́ rẹ.”+
11 Nebukadinésárì* ọba Bábílónì sì pàṣẹ fún Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ nípa Jeremáyà, pé: 12 “Mú un, kí o sì tọ́jú rẹ̀; má hùwà ìkà sí i, kí o sì fún un ní ohunkóhun tó bá béèrè lọ́wọ́ rẹ.”+