Jeremáyà 32:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní àkókò yẹn, àwọn ọmọ ogun ọba Bábílónì dó ti Jerúsálẹ́mù, wòlíì Jeremáyà sì wà ní àhámọ́ ní Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́+ ní ilé* ọba Júdà. Jeremáyà 37:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí náà, Ọba Sedekáyà ní kí wọ́n fi Jeremáyà sínú àhámọ́ ní Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́,+ wọ́n sì ń fún un ní ìṣù búrẹ́dì ribiti kan lójúmọ́ láti òpópónà àwọn tó ń ṣe búrẹ́dì,+ títí gbogbo búrẹ́dì ìlú náà fi tán.+ Jeremáyà kò sì kúrò ní Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́.
2 Ní àkókò yẹn, àwọn ọmọ ogun ọba Bábílónì dó ti Jerúsálẹ́mù, wòlíì Jeremáyà sì wà ní àhámọ́ ní Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́+ ní ilé* ọba Júdà.
21 Nítorí náà, Ọba Sedekáyà ní kí wọ́n fi Jeremáyà sínú àhámọ́ ní Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́,+ wọ́n sì ń fún un ní ìṣù búrẹ́dì ribiti kan lójúmọ́ láti òpópónà àwọn tó ń ṣe búrẹ́dì,+ títí gbogbo búrẹ́dì ìlú náà fi tán.+ Jeremáyà kò sì kúrò ní Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́.