2 Àwọn Ọba 25:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ní oṣù keje, Íṣímáẹ́lì+ ọmọ Netanáyà ọmọ Élíṣámà, tó wá láti ìdílé ọba,* wá pẹ̀lú àwọn ọkùnrin mẹ́wàá míì, wọ́n ṣá Gẹdaláyà balẹ̀, ó sì kú, òun àti àwọn Júù àti àwọn ará Kálídíà tó wà pẹ̀lú rẹ̀ ní Mísípà.+
25 Ní oṣù keje, Íṣímáẹ́lì+ ọmọ Netanáyà ọmọ Élíṣámà, tó wá láti ìdílé ọba,* wá pẹ̀lú àwọn ọkùnrin mẹ́wàá míì, wọ́n ṣá Gẹdaláyà balẹ̀, ó sì kú, òun àti àwọn Júù àti àwọn ará Kálídíà tó wà pẹ̀lú rẹ̀ ní Mísípà.+