-
Jeremáyà 40:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Jóhánánì ọmọ Káréà àti gbogbo olórí àwọn ọmọ ogun tó wà ní pápá wá sọ́dọ̀ Gẹdaláyà ní Mísípà.
-
-
Jeremáyà 43:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Asaráyà ọmọ Hóṣáyà àti Jóhánánì+ ọmọ Káréà pẹ̀lú gbogbo àwọn ọkùnrin tó jẹ́ agbéraga wá sọ fún Jeremáyà pé: “Irọ́ lò ń pa! Jèhófà Ọlọ́run wa kò rán ọ kí o sọ pé, ‘Ẹ má lọ sí Íjíbítì láti máa gbé ibẹ̀.’
-