Jeremáyà 19:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àwọn ilé Jerúsálẹ́mù àti ilé àwọn ọba Júdà á sì di aláìmọ́ bí ibí yìí, bíi Tófétì,+ àní títí kan gbogbo ilé tí wọ́n ń rú ẹbọ ní òrùlé rẹ̀ sí gbogbo ọmọ ogun ọ̀run,+ tí wọ́n sì ti ń da ọrẹ ohun mímu sí àwọn ọlọ́run míì.’”+
13 Àwọn ilé Jerúsálẹ́mù àti ilé àwọn ọba Júdà á sì di aláìmọ́ bí ibí yìí, bíi Tófétì,+ àní títí kan gbogbo ilé tí wọ́n ń rú ẹbọ ní òrùlé rẹ̀ sí gbogbo ọmọ ogun ọ̀run,+ tí wọ́n sì ti ń da ọrẹ ohun mímu sí àwọn ọlọ́run míì.’”+