ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 48:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 Gbọ́ èyí, ìwọ ilé Jékọ́bù,

      Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fi orúkọ Ísírẹ́lì pe ara yín +

      Àti ẹ̀yin tí ẹ jáde látinú omi* Júdà,

      Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fi orúkọ Jèhófà búra,+

      Tí ẹ sì ń ké pe Ọlọ́run Ísírẹ́lì,

      Bó tiẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe ní òtítọ́ àti òdodo.+

       2 Torí wọ́n ń fi ìlú mímọ́+ pe ara wọn,

      Wọ́n sì ń wá ìtìlẹyìn Ọlọ́run Ísírẹ́lì,+

      Tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.

  • Jeremáyà 5:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Bí wọ́n bá tiẹ̀ sọ pé: “Bí Jèhófà ti wà láàyè!”

      Irọ́ ni wọ́n ṣì máa pa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́