Jeremáyà 32:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 mo sì fún Bárúkù,+ ọmọ Neráyà,+ ọmọ Maseáyà ní ìwé àdéhùn náà lójú Hánámélì ọmọ arákùnrin bàbá mi àti lójú àwọn ẹlẹ́rìí tó buwọ́ lu ìwé àdéhùn náà àti lójú gbogbo àwọn Júù tó jókòó sí Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́.+ Jeremáyà 43:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Bárúkù+ ọmọ Neráyà ló ń dẹ ọ́ sí wa láti fi wá lé ọwọ́ àwọn ará Kálídíà, kí wọ́n lè pa wá tàbí kí wọ́n kó wa lọ sí ìgbèkùn ní Bábílónì.”+
12 mo sì fún Bárúkù,+ ọmọ Neráyà,+ ọmọ Maseáyà ní ìwé àdéhùn náà lójú Hánámélì ọmọ arákùnrin bàbá mi àti lójú àwọn ẹlẹ́rìí tó buwọ́ lu ìwé àdéhùn náà àti lójú gbogbo àwọn Júù tó jókòó sí Àgbàlá Ẹ̀ṣọ́.+
3 Bárúkù+ ọmọ Neráyà ló ń dẹ ọ́ sí wa láti fi wá lé ọwọ́ àwọn ará Kálídíà, kí wọ́n lè pa wá tàbí kí wọ́n kó wa lọ sí ìgbèkùn ní Bábílónì.”+