-
Jeremáyà 36:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Yàtọ̀ síyẹn, ọba pàṣẹ fún Jéráméélì ọmọ ọba àti Seráyà ọmọ Ásíríẹ́lì pẹ̀lú Ṣelemáyà ọmọ Ábídélì pé kí wọ́n mú Bárúkù akọ̀wé àti wòlíì Jeremáyà, àmọ́ Jèhófà fi wọ́n pa mọ́.+
-