Jeremáyà 45:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ọ̀rọ̀ tí wòlíì Jeremáyà sọ fún Bárúkù+ ọmọ Neráyà nìyí, nígbà tó ń kọ ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà ń sọ fún un sínú ìwé+ ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà:
45 Ọ̀rọ̀ tí wòlíì Jeremáyà sọ fún Bárúkù+ ọmọ Neráyà nìyí, nígbà tó ń kọ ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà ń sọ fún un sínú ìwé+ ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà: