Jeremáyà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo àwọn èèyàn Júdà ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà, ìyẹn ní ọdún kìíní Nebukadinésárì* ọba Bábílónì. Jeremáyà 36:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ó ṣẹlẹ̀ pé ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà, Jèhófà bá Jeremáyà sọ̀rọ̀, ó ní:
25 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo àwọn èèyàn Júdà ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà, ìyẹn ní ọdún kìíní Nebukadinésárì* ọba Bábílónì.