2 Àwọn Ọba 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà ayé Jèhóákímù, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì wá gbéjà kò ó, Jèhóákímù sì fi ọdún mẹ́ta ṣe ìránṣẹ́ fún un. Àmọ́, ó yí pa dà, ó sì ṣọ̀tẹ̀. Jeremáyà 36:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ó ṣẹlẹ̀ pé ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà, Jèhófà bá Jeremáyà sọ̀rọ̀, ó ní: Jeremáyà 46:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Sí Íjíbítì,+ nípa àwọn ọmọ ogun Fáráò Nékò + ọba Íjíbítì, tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò Yúfírétì, ẹni tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ṣẹ́gun ní Kákémíṣì, ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà: Dáníẹ́lì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ní ọdún kẹta àkóso Jèhóákímù+ ọba Júdà, Nebukadinésárì ọba Bábílónì wá sí Jerúsálẹ́mù, ó sì pàgọ́ tì í.+
24 Nígbà ayé Jèhóákímù, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì wá gbéjà kò ó, Jèhóákímù sì fi ọdún mẹ́ta ṣe ìránṣẹ́ fún un. Àmọ́, ó yí pa dà, ó sì ṣọ̀tẹ̀.
2 Sí Íjíbítì,+ nípa àwọn ọmọ ogun Fáráò Nékò + ọba Íjíbítì, tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò Yúfírétì, ẹni tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ṣẹ́gun ní Kákémíṣì, ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà:
1 Ní ọdún kẹta àkóso Jèhóákímù+ ọba Júdà, Nebukadinésárì ọba Bábílónì wá sí Jerúsálẹ́mù, ó sì pàgọ́ tì í.+