2 Kíróníkà 35:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Lẹ́yìn gbogbo nǹkan yìí, tí Jòsáyà ti múra tẹ́ńpìlì* náà sílẹ̀, Nékò+ ọba Íjíbítì wá jà ní Kákémíṣì lẹ́gbẹ̀ẹ́ Yúfírétì. Ni Jòsáyà bá jáde lọ dojú kọ ọ́.+
20 Lẹ́yìn gbogbo nǹkan yìí, tí Jòsáyà ti múra tẹ́ńpìlì* náà sílẹ̀, Nékò+ ọba Íjíbítì wá jà ní Kákémíṣì lẹ́gbẹ̀ẹ́ Yúfírétì. Ni Jòsáyà bá jáde lọ dojú kọ ọ́.+