32 Lẹ́yìn náà, Jeremáyà mú àkájọ ìwé míì, ó fún Bárúkù ọmọ Neráyà, akọ̀wé,+ ó sì ń kọ ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà ń sọ fún un sínú rẹ̀, ó kọ gbogbo ọ̀rọ̀ inú àkájọ ìwé tí Jèhóákímù ọba Júdà sun nínú iná.+ Ọ̀rọ̀ púpọ̀ tó dà bí èyí tó wà níbẹ̀ tẹ́lẹ̀ ni a sì fi kún un.