Àìsáyà 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó yá, ẹ jọ̀ọ́, ẹ jẹ́ kí n sọ fún yín,Ohun tí màá ṣe sí ọgbà àjàrà mi: Màá mú ọgbà tó yí i ká kúrò,Màá sì dáná sun ún.+ Màá fọ́ ògiri olókùúta rẹ̀,Wọ́n sì máa tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀. Jeremáyà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ìwọ̀nyí ni ọ̀rọ̀ Jeremáyà,* ọmọ Hilikáyà, ọ̀kan lára àwọn àlùfáà tó wà ní Ánátótì,+ ní ilẹ̀ Bẹ́ńjámínì. Jeremáyà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wò ó, mo ti fàṣẹ yàn ọ́ lónìí lórí àwọn orílẹ̀-èdè àti lórí àwọn ìjọba, láti fà tu àti láti bì wó, láti pa run àti láti ya lulẹ̀, láti kọ́ àti láti gbìn.”+
5 Ó yá, ẹ jọ̀ọ́, ẹ jẹ́ kí n sọ fún yín,Ohun tí màá ṣe sí ọgbà àjàrà mi: Màá mú ọgbà tó yí i ká kúrò,Màá sì dáná sun ún.+ Màá fọ́ ògiri olókùúta rẹ̀,Wọ́n sì máa tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀.
1 Ìwọ̀nyí ni ọ̀rọ̀ Jeremáyà,* ọmọ Hilikáyà, ọ̀kan lára àwọn àlùfáà tó wà ní Ánátótì,+ ní ilẹ̀ Bẹ́ńjámínì.
10 Wò ó, mo ti fàṣẹ yàn ọ́ lónìí lórí àwọn orílẹ̀-èdè àti lórí àwọn ìjọba, láti fà tu àti láti bì wó, láti pa run àti láti ya lulẹ̀, láti kọ́ àti láti gbìn.”+