ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 18:7-10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Nígbà tí mo bá sọ pé màá fa orílẹ̀-èdè kan tàbí ìjọba kan tu, tí mo sọ pé màá ya á lulẹ̀, tí màá sì pa á run,+ 8 bí orílẹ̀-èdè náà bá jáwọ́ nínú ìwà burúkú rẹ̀ tí mo kìlọ̀ fún un, èmi náà á pèrò dà* lórí àjálù tí mo ti sọ pé màá jẹ́ kó dé bá a.+ 9 Àmọ́, tí mo bá sọ pé màá kọ́ orílẹ̀-èdè kan tàbí ìjọba kan, tí mo sọ pé màá gbìn ín, 10 tó bá ṣe ohun tó burú lójú mi, tí kò sì ṣègbọràn sí ohùn mi, ńṣe ni màá pèrò dà* nípa ohun rere tí mo sọ pé màá ṣe fún un.’

  • Jeremáyà 24:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Bí àwọn ọ̀pọ̀tọ́ yìí ṣe dára, bẹ́ẹ̀ ni màá ṣe fi ojú tó dára wo àwọn ará Júdà tó wà ní ìgbèkùn, àwọn tí mo rán lọ kúrò ní ibí yìí sí ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà. 6 Ojú mi yóò wà lára wọn láti ṣe wọ́n lóore, màá sì mú kí wọ́n pa dà sí ilẹ̀ yìí.+ Màá gbé wọn ró, mi ò sì ní ya wọ́n lulẹ̀, màá gbìn wọ́n, mi ò sì ní fà wọ́n tu.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́