Jẹ́nẹ́sísì 37:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Wọ́n wá jókòó láti jẹun. Nígbà tí wọ́n wòkè, wọ́n rí àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì+ tó ń rìnrìn àjò tí wọ́n ń bọ̀ láti Gílíádì. Àwọn ràkúnmí wọn ru gọ́ọ̀mù lábídánọ́mù, básámù àti èèpo+ igi olóje, wọ́n ń lọ sí Íjíbítì. Jeremáyà 8:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ṣé kò sí básámù* ní Gílíádì+ ni? Àbí ṣé kò sí oníwòsàn* níbẹ̀ ni?+ Kí ló wá dé tí ara ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi kò fi tíì yá?+
25 Wọ́n wá jókòó láti jẹun. Nígbà tí wọ́n wòkè, wọ́n rí àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì+ tó ń rìnrìn àjò tí wọ́n ń bọ̀ láti Gílíádì. Àwọn ràkúnmí wọn ru gọ́ọ̀mù lábídánọ́mù, básámù àti èèpo+ igi olóje, wọ́n ń lọ sí Íjíbítì.
22 Ṣé kò sí básámù* ní Gílíádì+ ni? Àbí ṣé kò sí oníwòsàn* níbẹ̀ ni?+ Kí ló wá dé tí ara ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi kò fi tíì yá?+