44Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo Júù tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ìyẹn àwọn tó ń gbé ní Mígídólì,+ ní Tápánẹ́sì,+ ní Nófì*+ àti ní ilẹ̀ Pátírọ́sì,+ pé:
10 Torí náà, màá bá ìwọ àti odò Náílì rẹ jà, màá mú kí ilẹ̀ Íjíbítì dá páropáro kó sì gbẹ, yóò di ahoro,+ láti Mígídólì+ dé Síénè,+ títí dé ààlà Etiópíà.