Àìsáyà 16:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 A ti gbọ́ bí Móábù ṣe ń gbéra ga, ó ń gbéra ga gan-an;+Bó ṣe ń gbéra ga, tó ń yangàn, tó sì ń bínú;+Àmọ́ pàbó ni ọ̀rọ̀ asán rẹ̀ máa já sí.
6 A ti gbọ́ bí Móábù ṣe ń gbéra ga, ó ń gbéra ga gan-an;+Bó ṣe ń gbéra ga, tó ń yangàn, tó sì ń bínú;+Àmọ́ pàbó ni ọ̀rọ̀ asán rẹ̀ máa já sí.