Émọ́sì 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Torí náà, màá rán iná sí Móábù,Á sì jó àwọn ilé gogoro tó láàbò ti Kíríọ́tì+ run;Móábù á kú sínú ariwo,Nígbà tí ariwo bá sọ nítorí ogun, tí ìró ìwo sì dún.+
2 Torí náà, màá rán iná sí Móábù,Á sì jó àwọn ilé gogoro tó láàbò ti Kíríọ́tì+ run;Móábù á kú sínú ariwo,Nígbà tí ariwo bá sọ nítorí ogun, tí ìró ìwo sì dún.+