Àìsáyà 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Móábù:+ Torí a ti pa á run ní òru kan,A ti pa Árì+ ti Móábù lẹ́nu mọ́. Torí a ti pa á run ní òru kan,A ti pa Kírì+ ti Móábù lẹ́nu mọ́.
15 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Móábù:+ Torí a ti pa á run ní òru kan,A ti pa Árì+ ti Móábù lẹ́nu mọ́. Torí a ti pa á run ní òru kan,A ti pa Kírì+ ti Móábù lẹ́nu mọ́.