Ìdárò 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Gbogbo àwọn tó ń kọjá lọ lójú ọ̀nà ń fi ọ́ ṣẹ̀sín, wọ́n sì ń pàtẹ́wọ́.+ Wọ́n ń súfèé nítorí ìyàlẹ́nu,+ wọ́n sì ń mi orí wọn sí ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù, pé: “Ṣé ìlú yìí ni wọ́n máa ń sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Ẹwà rẹ̀ pé, ó jẹ́ ayọ̀ gbogbo ayé’?”+ Sefanáyà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Mo ti gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn láti ẹnu Móábù+ àti èébú àwọn ọmọ Ámónì,+Àwọn tó kẹ́gàn àwọn èèyàn mi, tí wọ́n sì ń halẹ̀ mọ́ wọn láti gba ilẹ̀ wọn.+
15 Gbogbo àwọn tó ń kọjá lọ lójú ọ̀nà ń fi ọ́ ṣẹ̀sín, wọ́n sì ń pàtẹ́wọ́.+ Wọ́n ń súfèé nítorí ìyàlẹ́nu,+ wọ́n sì ń mi orí wọn sí ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù, pé: “Ṣé ìlú yìí ni wọ́n máa ń sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Ẹwà rẹ̀ pé, ó jẹ́ ayọ̀ gbogbo ayé’?”+
8 “Mo ti gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn láti ẹnu Móábù+ àti èébú àwọn ọmọ Ámónì,+Àwọn tó kẹ́gàn àwọn èèyàn mi, tí wọ́n sì ń halẹ̀ mọ́ wọn láti gba ilẹ̀ wọn.+