Jeremáyà 48:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wọn ò yin Móábù mọ́. Hẹ́ṣíbónì+ ni wọ́n ti gbèrò ìṣubú rẹ̀, pé: ‘Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a pa á run, kí ó má ṣe jẹ́ orílẹ̀-èdè mọ́.’ Kí ìwọ Mádíménì pẹ̀lú dákẹ́,Torí idà ń tẹ̀ lé ọ. 3 Ìró ẹkún wá láti Hórónáímù,+Ti ìparun àti ìwópalẹ̀ tó bùáyà.
2 Wọn ò yin Móábù mọ́. Hẹ́ṣíbónì+ ni wọ́n ti gbèrò ìṣubú rẹ̀, pé: ‘Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a pa á run, kí ó má ṣe jẹ́ orílẹ̀-èdè mọ́.’ Kí ìwọ Mádíménì pẹ̀lú dákẹ́,Torí idà ń tẹ̀ lé ọ. 3 Ìró ẹkún wá láti Hórónáímù,+Ti ìparun àti ìwópalẹ̀ tó bùáyà.