Àìsáyà 15:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọkàn mi ń ké jáde torí Móábù. Àwọn tó sá níbẹ̀ ti sá lọ sí Sóárì+ àti Ẹgilati-ṣẹ́líṣíyà+ lọ́hùn-ún lọ́hùn-ún. Wọ́n ń sunkún bí wọ́n ṣe ń gòkè lọ sí Lúhítì;Wọ́n ń ké lójú ọ̀nà Hórónáímù torí àjálù náà.+ Jeremáyà 48:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 “‘Igbe kan dún láti Hẹ́ṣíbónì+ títí lọ dé Éléálè.+ Wọ́n gbé ohùn wọn sókè tó fi dé Jáhásì,+Láti Sóárì dé Hórónáímù,+ dé Ẹgilati-ṣẹ́líṣíyà. Àní omi Nímúrímù máa gbẹ.+
5 Ọkàn mi ń ké jáde torí Móábù. Àwọn tó sá níbẹ̀ ti sá lọ sí Sóárì+ àti Ẹgilati-ṣẹ́líṣíyà+ lọ́hùn-ún lọ́hùn-ún. Wọ́n ń sunkún bí wọ́n ṣe ń gòkè lọ sí Lúhítì;Wọ́n ń ké lójú ọ̀nà Hórónáímù torí àjálù náà.+
34 “‘Igbe kan dún láti Hẹ́ṣíbónì+ títí lọ dé Éléálè.+ Wọ́n gbé ohùn wọn sókè tó fi dé Jáhásì,+Láti Sóárì dé Hórónáímù,+ dé Ẹgilati-ṣẹ́líṣíyà. Àní omi Nímúrímù máa gbẹ.+