Jeremáyà 48:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 “‘Igbe kan dún láti Hẹ́ṣíbónì+ títí lọ dé Éléálè.+ Wọ́n gbé ohùn wọn sókè tó fi dé Jáhásì,+Láti Sóárì dé Hórónáímù,+ dé Ẹgilati-ṣẹ́líṣíyà. Àní omi Nímúrímù máa gbẹ.+
34 “‘Igbe kan dún láti Hẹ́ṣíbónì+ títí lọ dé Éléálè.+ Wọ́n gbé ohùn wọn sókè tó fi dé Jáhásì,+Láti Sóárì dé Hórónáímù,+ dé Ẹgilati-ṣẹ́líṣíyà. Àní omi Nímúrímù máa gbẹ.+