Jeremáyà 25:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí náà, mo gba ife náà lọ́wọ́ Jèhófà, mo sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè tí Jèhófà rán mi sí mu ún:+ Jeremáyà 25:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 gbogbo ọba Símírì, gbogbo ọba Élámù+ àti gbogbo ọba àwọn ará Mídíà,+