Jeremáyà 49:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún wòlíì Jeremáyà nípa Élámù+ ní ìbẹ̀rẹ̀ ìṣàkóso Sedekáyà+ ọba Júdà, nìyí: