ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 10:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Àwọn ọmọ Ṣémù ni Élámù,+ Áṣúrì,+ Ápákíṣádì,+ Lúdì àti Árámù.+

  • Àìsáyà 21:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 A ti sọ ìran kan tó le fún mi:

      Ọ̀dàlẹ̀ ń dalẹ̀,

      Apanirun sì ń pani run.

      Gòkè lọ, ìwọ Élámù! Gbógun tini, ìwọ Mídíà!+

      Màá fòpin sí gbogbo ẹ̀dùn ọkàn tó mú kó bá àwọn èèyàn.+

  • Jeremáyà 25:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Torí náà, mo gba ife náà lọ́wọ́ Jèhófà, mo sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè tí Jèhófà rán mi sí mu ún:+

  • Jeremáyà 25:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 gbogbo ọba Símírì, gbogbo ọba Élámù+ àti gbogbo ọba àwọn ará Mídíà,+

  • Ìsíkíẹ́lì 32:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 “‘Élámù+ àti gbogbo èèyàn rẹ̀ tó pọ̀ rẹpẹtẹ wà níbẹ̀ tí wọ́n yí sàréè rẹ̀ ká, gbogbo wọn ni wọ́n fi idà pa. Wọ́n ti lọ sí ilẹ̀ tó wà nísàlẹ̀ láìdádọ̀dọ́,* àwọn tí wọ́n dẹ́rù bani ní ilẹ̀ alààyè. Ojú á wá tì wọ́n pẹ̀lú àwọn tó ń lọ sínú kòtò.*

  • Dáníẹ́lì 8:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Mo rí ìran náà, bí mo sì ṣe ń wò ó, mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* tó wà ní ìpínlẹ̀* Élámù;+ mo rí ìran náà, mo sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ipadò Úláì.

  • Ìṣe 2:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Báwo ló ṣe wá jẹ́ pé kálukú wa ń gbọ́ èdè ìbílẹ̀* rẹ̀? 9 Àwọn tó wà pẹ̀lú wa ni àwọn ará Pátíà, àwọn ará Mídíà+ àti àwọn ọmọ Élámù,+ àwọn tó ń gbé Mesopotámíà, Jùdíà àti Kapadókíà, Pọ́ńtù àti ìpínlẹ̀ Éṣíà,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́