Dáníẹ́lì 8:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní ọdún kẹta àkóso Ọba Bẹliṣásárì,+ èmi Dáníẹ́lì rí ìran kan, lẹ́yìn èyí tí mo kọ́kọ́ rí.+ 2 Mo rí ìran náà, bí mo sì ṣe ń wò ó, mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* tó wà ní ìpínlẹ̀* Élámù;+ mo rí ìran náà, mo sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ipadò Úláì.
8 Ní ọdún kẹta àkóso Ọba Bẹliṣásárì,+ èmi Dáníẹ́lì rí ìran kan, lẹ́yìn èyí tí mo kọ́kọ́ rí.+ 2 Mo rí ìran náà, bí mo sì ṣe ń wò ó, mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* tó wà ní ìpínlẹ̀* Élámù;+ mo rí ìran náà, mo sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ipadò Úláì.