Ìdárò 1:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àwọn èèyàn ti gbọ́ bí mo ṣe ń kẹ́dùn; kò sí ẹnì kankan tó máa tù mí nínú. Gbogbo àwọn ọ̀tá mi ti gbọ́ nípa àjálù tó dé bá mi. Inú wọn dùn, nítorí o mú kí ó ṣẹlẹ̀.+ Àmọ́, o máa mú ọjọ́ tí o kéde wá,+ tí wọ́n á dà bí mo ṣe dà.+
21 Àwọn èèyàn ti gbọ́ bí mo ṣe ń kẹ́dùn; kò sí ẹnì kankan tó máa tù mí nínú. Gbogbo àwọn ọ̀tá mi ti gbọ́ nípa àjálù tó dé bá mi. Inú wọn dùn, nítorí o mú kí ó ṣẹlẹ̀.+ Àmọ́, o máa mú ọjọ́ tí o kéde wá,+ tí wọ́n á dà bí mo ṣe dà.+