Àìsáyà 47:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Wá gbọ́ èyí, ìwọ ẹni tó fẹ́ràn fàájì,+Tó jókòó láìséwu, tó ń sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Èmi ni ẹni náà, kò sí ẹlòmíì.+ Mi ò ní di opó. Mi ò ní ṣòfò ọmọ láé.”+
8 Wá gbọ́ èyí, ìwọ ẹni tó fẹ́ràn fàájì,+Tó jókòó láìséwu, tó ń sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Èmi ni ẹni náà, kò sí ẹlòmíì.+ Mi ò ní di opó. Mi ò ní ṣòfò ọmọ láé.”+