Jeremáyà 51:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Bábílónì á sì di òkìtì òkúta,+Ibùgbé àwọn ajáko,*+Ohun àríbẹ̀rù àti ohun àrísúfèé,Tí ẹnì kankan kò ní gbé ibẹ̀.+
37 Bábílónì á sì di òkìtì òkúta,+Ibùgbé àwọn ajáko,*+Ohun àríbẹ̀rù àti ohun àrísúfèé,Tí ẹnì kankan kò ní gbé ibẹ̀.+