Jeremáyà 25:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “‘Ṣùgbọ́n tí àádọ́rin (70) ọdún bá pé,+ màá pe ọba Bábílónì àti orílẹ̀-èdè yẹn wá jíhìn* nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,’+ ni Jèhófà wí, ‘màá sì sọ ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà di ahoro títí láé.+ Jeremáyà 50:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹ kígbe ogun mọ́ ọn láti ibi gbogbo. Ó ti juwọ́ sílẹ̀.* Àwọn òpó rẹ̀ ti ṣubú, àwọn ògiri rẹ̀ sì ti ya lulẹ̀,+Nítorí ẹ̀san Jèhófà ni.+ Ẹ gbẹ̀san lára rẹ̀. Bí ó ti ṣe síni ni kí ẹ ṣe sí i gẹ́lẹ́.+
12 “‘Ṣùgbọ́n tí àádọ́rin (70) ọdún bá pé,+ màá pe ọba Bábílónì àti orílẹ̀-èdè yẹn wá jíhìn* nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,’+ ni Jèhófà wí, ‘màá sì sọ ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà di ahoro títí láé.+
15 Ẹ kígbe ogun mọ́ ọn láti ibi gbogbo. Ó ti juwọ́ sílẹ̀.* Àwọn òpó rẹ̀ ti ṣubú, àwọn ògiri rẹ̀ sì ti ya lulẹ̀,+Nítorí ẹ̀san Jèhófà ni.+ Ẹ gbẹ̀san lára rẹ̀. Bí ó ti ṣe síni ni kí ẹ ṣe sí i gẹ́lẹ́.+