Míkà 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Fi ọ̀pá rẹ ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn èèyàn rẹ, agbo ẹran tó jẹ́ ogún rẹ,+Tó ń dá gbé inú igbó, láàárín ọgbà eléso. Jẹ́ kí Báṣánì àti Gílíádì+ fún wọn ní oúnjẹ bíi ti àtijọ́.
14 Fi ọ̀pá rẹ ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn èèyàn rẹ, agbo ẹran tó jẹ́ ogún rẹ,+Tó ń dá gbé inú igbó, láàárín ọgbà eléso. Jẹ́ kí Báṣánì àti Gílíádì+ fún wọn ní oúnjẹ bíi ti àtijọ́.