Jeremáyà 50:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Màá mú Ísírẹ́lì pa dà sí ibi ìjẹko rẹ̀,+ á jẹko ní Kámẹ́lì àti ní Báṣánì,+ á* sì ní ìtẹ́lọ́rùn lórí àwọn òkè Éfúrémù+ àti ti Gílíádì.’”+ Ìsíkíẹ́lì 34:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Èmi yóò yan olùṣọ́ àgùntàn kan fún wọn,+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi,+ yóò sì máa bọ́ wọn. Òun fúnra rẹ̀ máa bọ́ wọn, ó sì máa di olùṣọ́ àgùntàn wọn.+
19 Màá mú Ísírẹ́lì pa dà sí ibi ìjẹko rẹ̀,+ á jẹko ní Kámẹ́lì àti ní Báṣánì,+ á* sì ní ìtẹ́lọ́rùn lórí àwọn òkè Éfúrémù+ àti ti Gílíádì.’”+
23 Èmi yóò yan olùṣọ́ àgùntàn kan fún wọn,+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi,+ yóò sì máa bọ́ wọn. Òun fúnra rẹ̀ máa bọ́ wọn, ó sì máa di olùṣọ́ àgùntàn wọn.+