Jòhánù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Èmi ni olùṣọ́ àgùntàn àtàtà;+ olùṣọ́ àgùntàn àtàtà máa ń fi ẹ̀mí* rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn àgùntàn.+ Hébérù 13:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kí Ọlọ́run àlàáfíà, tó jí Jésù Olúwa wa dìde, olùṣọ́ àgùntàn ńlá+ fún àwọn àgùntàn, pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú àìnípẹ̀kun, 1 Pétérù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Tí a bá sì fi olórí olùṣọ́ àgùntàn+ hàn kedere, ẹ máa gba adé ògo tí kì í ṣá.+ Ìfihàn 7:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 torí Ọ̀dọ́ Àgùntàn,+ tó wà ní àárín ìtẹ́ náà, máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn,+ ó sì máa darí wọn lọ sí àwọn ìsun* omi ìyè.+ Ọlọ́run sì máa nu gbogbo omijé kúrò ní ojú wọn.”+
20 Kí Ọlọ́run àlàáfíà, tó jí Jésù Olúwa wa dìde, olùṣọ́ àgùntàn ńlá+ fún àwọn àgùntàn, pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú àìnípẹ̀kun,
17 torí Ọ̀dọ́ Àgùntàn,+ tó wà ní àárín ìtẹ́ náà, máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn,+ ó sì máa darí wọn lọ sí àwọn ìsun* omi ìyè.+ Ọlọ́run sì máa nu gbogbo omijé kúrò ní ojú wọn.”+