ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 34:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Jèhófà ní idà kan; ẹ̀jẹ̀ máa bò ó.

      Ọ̀rá+ máa bò ó,

      Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọ àgbò àti ewúrẹ́ máa bò ó,

      Ọ̀rá kíndìnrín àwọn àgbò máa bò ó.

      Torí pé Jèhófà ní ẹbọ ní Bósírà,

      Ó máa pa ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ ní ilẹ̀ Édómù.+

       7 Àwọn akọ màlúù igbó máa bá wọn sọ̀ kalẹ̀,

      Àwọn akọ ọmọ màlúù pẹ̀lú àwọn alágbára.

      Ẹ̀jẹ̀ máa rin ilẹ̀ wọn gbingbin,

      Ọ̀rá sì máa rin iyẹ̀pẹ̀ wọn gbingbin.”

  • Ìsíkíẹ́lì 39:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ẹ ó jẹ ẹran àwọn alágbára, ẹ ó sì mu ẹ̀jẹ̀ àwọn ìjòyè ayé, àwọn àgbò, àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn, àwọn òbúkọ àti àwọn akọ màlúù, gbogbo ẹran Báṣánì tí wọ́n bọ́ sanra.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́